Ile Asé Osun Opara

Ile Asé Osun Opara

sábado, 29 de janeiro de 2011

Sirè..





O que é Sìrè?
Sìrè no candomblé brasileiro equivale à festa do Orisá. Dançar, brincar, festejar, jogar, divertimento, ou seja, o início das louvações as divindades. no Ilè Asé Osún Opàrá Sìrè são apenas 3 cantigas para cada Orisá, caso contrário vira "Hun" de Orisá, se não depois não tem muito o que cantar, apenas para alguns....


Ogun
Ogun Ajo e monriwo, Alaakoro ajo e monriwo,
Ogun pa le pa loonon, ogun ajo e monriwo
Ele ki fi eje we

Awa nsírè Ogun o, eru jojo
Awa nsírè Ogun o, eru jojo
Erunjeje.

Alaada meji meji
A L´Ogun meje Ire.

Osoosi
Ofa re ye ye figbo dode figbo
Ofa re ye ye ko sé omorodé

Ewa tire oke, ewa tire, ni lé igbo re ó

Ara wa won ní jé ki ofa re won, ofá re ye je ni won
Ara wa won ní jé ki ofa re won, ofá re ye je ni won
Ara wa won ní jé ki ofa re won, Olowo o
Ara wa won ní jé ki ofa re won.

Omolu
A ji dagoloonon ki wa sawo oro
Dago ile ile, dagoloonon ki wa sawo oro
Dago ile ile.

Omolu mo ni fi ni yin
Fara fara faroti, omolu akara e e 
Fara fara faroti.

E fara loko, fara loko,
Pa zu e, pa zu e
Omolu araiye
Pa zu e, pa zu e


Osonyin
Ábèbè nbó, Ábèbè nbó
Ewe Ábèbè,
Ábèbè nbó, Ábèbè nbó
Ewe Ábèbè

Mo je ewe epe mo sonra o, Mo je ewe epe mo sonra
Epe lo be wa, epe lo ya mi, Mo je ewe epe mo sonra

Sá ore Pepe
Ope li ope lepe
Sá òrè pepe
Opè li ope Sango

Iroko
Iroko
Baba la kodè

Eró iroko iso
Ero iroko ki silé

Igi mon
Iroko ola sú

Osùmárè
Araka do bo orun
Ki lo da de owo, Osùmárè o o

E sin a bo re kun, gberun lé

Alaakoro lé èmi ò alaakoro lè ìwo
Alaakoro lé èmi ò alaakoro lè ìwo

Nàna
E nana ewa o
Adaba o o oro lese

E olowo oro lese, nana olowo
E e oro da ka ya, nana olowo

Eni koríko odo ki walé, omon nílè ko rajo,
Nàná ikú rè omon nílè ko rajo, ko rajo
ko rajo, o fele le, ko rajo.

Òsún
Yeye, yeye yiye ó ó, olúféwa àsé omi odò
E oba kó só ayaba ó, olúféwa àsé omi odò.

E ye oja re, ya ele majo obè mo ro

Omi fa were
Omi fa were omiro
Aride gbe o o

Oba
Oba eleko ajaosi
Soba eleko ajaosi
Oro moba
Sa moba oba eleko ajaosi

E nu were
Ofá were
E nu were
Ofá were

E nu ofa fara man
Oba loja la oje

Yewa
Iyewa iyewa ma ajo
Iyewa iyewa, olowo
Iyewa iyewa ma ajo
Iyewa iyewa
Oba olowo, awo lese
Iyewa iyewa ma ajo

Iyewa  ni fa toto lo bewa e
Olu aiye iyewa ni fa toto lo bewa e
Olu aiye

Iyewa masa
Awa masa
Amu re le o

Oya
Oya koro n le Ogere ge
Oya koro n la oga raga
Omobirin sala koro n le
Oge rege
Oya komo re lo

Ta ni a pada loodo Oya,
Odo ho ya ya
Ta ni a pada loodo Oya,
Odo ho ya ya

Adupe ni ko gbe l´ajo
Oya ni ko gbe l´ajo
E loya

Yèmojá
Marele Mara bodo
Sa rena
Awoyo karabodo
Sare non e e
Oni a araye
Marele marabodo
Sa rena

Iyagba o de ire se
A kii e Yemoja
A koko pe ile gbe a o yo
Odo o fi, a sa were o


Sango
Orain a lode o
Bara eni já, eni a roko
Oba nu koso, nu re lê o
Bara eni já, eni a roko
Oni maa, ni mo eje
Bara eni já, eni a roko
Mo oya, mi mo oya, mo ye ku
Bara eni já, eni a roko
Meta meta, te ro oya
Bara eni já, eni a roko
Be lo koso murele
Bara eni já, eni a roko

Onika won bo lorun, kereje
Onika won bo lorun, kereje Agutan
Itetu pade wa lona, Onika si re le
Ibo si orain, a lode o
Bara eni já, eni a roko

Oba ser ela fehintin
Oba ser ela fehintin
Oba nwa aiye be lorun
Oba ser ela fehintin
Oba nwa aiye be lorun
Oba ser ela fehintin

Oba kere kere wa do, osi arole
Iya lodo mase, e ko ke re l´anu
S´oko Iyagba, iya lodo mase

A nwa wure, a nwa wura       
Obalube oba alado
Oba alado ri so, fun aiye
Oba alado ri so, fun aiye
Oba alado ri so, fun aiye

Osala
Me le kun tun, ala funfun baba
Baba duro de, baba duro de olorun
Baba duro de

Epo ekete o o
Baba ekete o o

Ajagunnon gba awa o o
Ajagunnon
Ajagunnon gba awa o o
Ajagunnon
Elemoso baba Oloorogun
Ajagunnon gba awa o o....


William Ti Ajagunnon
Asé..

Nenhum comentário:

Postar um comentário